reluwee

Yoruba

Ọ̀nà rélùwéè ní Yába, ìlú Èkó

Etymology

Borrowed from English railway.

Pronunciation

  • IPA(key): /ɾé.lù.wéè/

Noun

rélùwéè

  1. railway
    1. railroad
      Synonyms: ọ̀nà ojú irin, ọ̀nà rélùwéè
    2. train
      Synonyms: ọkọ̀ ojú irin, ọkọ̀ rélùwéè
      N kì í wọ rélùwéè ní òpin ọ̀sẹ̀. ― I don't take the train on weekends.