ebute

Yoruba

Èbúté lórílẹ̀-èdè Faran̄sé

Pronunciation

  • IPA(key): /è.bú.té/

Noun

èbúté

  1. (nautical) harbor, port, wharf
    Synonym: wọ́ọ̀fù
  2. (nautical) dock, dockyard
  3. destination
    Ṣé ìyá ẹ ti débùúté lálàáfíà? ― Did your mum reach her destination safely?

Derived terms

  • elubùúté
  • èbúté ọkọ̀
  • èbúté ọkọ̀-ojú-omi
  • Èbúté-Mẹta
  • èbútékọ̀