abo aja

Yoruba

Àwọn ọmọ abo ajá yìí ń mu ọyọ̀n ìyá wọn

Etymology

From abo (“female”) +‎ ajá (“dog”)

Pronunciation

  • IPA(key): /ā.bō ā.d͡ʒá/

Noun

abo ajá

  1. female dog
    Abo ajá yẹn bí ọmọ púpọ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá yìí ― That female dog gave birth to lots of puppies this last week