abo adiyẹ

Yoruba

Abo adìyẹ kan pẹ̀lú ọmọ rẹ̀

Etymology

From abo (“female”) +‎ adìyẹ (“chicken”)

Pronunciation

  • IPA(key): /ā.bō ā.dì.jɛ̄/

Noun

abo adìyẹ

  1. hen
    Synonyms: àgbébọ̀, obídìẹ
    Abo adìyẹ yẹn yín ẹyin púpọ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá yìí ― The hen laid a lot of eggs this last week